2 Chronicles 26:1

Ussiah ọba Juda

1 aNígbà náà gbogbo ènìyàn Juda mú Ussiah, ẹni tí ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́rìn-dínlógún wọ́n sì fi jẹ ọba ní ipò baba rẹ̀ Amasiah.
Copyright information for YorBMYO